Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:13 BMY

13 Ananíyà sì dáhùn wí pé, “Olúwa mo tí gbúrò ọkùnrin yìí lọ́dọ̀ ọ̀pọ̀ ènìyàn, gbogbo búrukú ti ó ṣe sí àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ ni Jerúsálémù.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:13 ni o tọ