Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:24 BMY

24 Ṣùgbọ́n ìdìtẹ̀ wọn di mímọ̀ fún Ṣọ́ọ̀lù. Wọ́n sì ń sọ́ ẹnu-bodè pẹ̀lú lọ́san àti lóru, wọ́n ń wá ọ̀nà láti pa á.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:24 ni o tọ