31 Nígbà náà ni ìjọ wà ni àlàáfíà yíká gbogbo Jùdíà àti ni Gálílì àti ni Samaríà, wọn ń fẹsẹ̀múlẹ̀, wọn ń rìn ní ìbẹ̀rù Olúwa, àti ni ìtùnú Ẹ̀mí Mímọ́, wọn ń pọ̀ sí i
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:31 ni o tọ