Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:4 BMY

4 Ó sì subú lulẹ̀, ó gbọ́ ohùn tí ó ń fọ̀ sí i pé, “Ṣọ́ọ̀lù, Ṣọ́ọ̀lù, è é ṣe ti ìwọ fi ń ṣe inúnibíni sí mi?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:4 ni o tọ