Ìfihàn 10:4 BMY

4 Nígbà tí àwọn àrá méje fọhùn, mo múra àti kọ̀wé: mo sì gbọ ohùn láti ọ̀run wá ń wí fún pé, “Fi èdìdì di ohun tí àwọn àrá méje náà sọ, má sì ṣe kọ wọ́n sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 10

Wo Ìfihàn 10:4 ni o tọ