15 Ańgẹ́lì kéje sì fọn ìpè; a sì gbọ́ ohùn ńlá láti ọ̀run, wí pé,“Ìjọba ayé di ti Olúwa wá, àti tí Kírísítì rẹ̀;òun yóò sì jọba láé àti láéláé!”
Ka pipe ipin Ìfihàn 11
Wo Ìfihàn 11:15 ni o tọ