Ìfihàn 13:11 BMY

11 Mo sì rí ẹranko mìíràn gòkè láti inú ilẹ̀ wá; ó sì ní ìwo méjì bí Ọ̀dọ́-Àgùntàn, ó sì ń sọ̀rọ̀ bí dírágónì.

Ka pipe ipin Ìfihàn 13

Wo Ìfihàn 13:11 ni o tọ