Ìfihàn 19:7 BMY

7 Ẹ jẹ́ kí a yọ̀, kí inú wa kí ó sì dùn gidigidi,kí a sì fi ògo fún un.Nítorí pé ìgbéyàwó Ọ̀dọ́-Àgùntàn dé,aya rẹ̀ sì ti múra tán.

Ka pipe ipin Ìfihàn 19

Wo Ìfihàn 19:7 ni o tọ