Ìfihàn 20:11 BMY

11 Mo sì rí ìtẹ́ funfun ńlá kan, àti ẹni tí ó jókòó lórí rẹ̀, níwájú ẹni tí ayé àti ọ̀run fò lọ; a kò sì rí àyè fún wọn mọ́.

Ka pipe ipin Ìfihàn 20

Wo Ìfihàn 20:11 ni o tọ