Ìfihàn 20:10 BMY

10 A sì wọ́ Èsù tí ó tàn wọ́n jẹ lọ sínú adágún iná àti súfúrù, níbi tí ẹranko àti wòlíì èké nì gbé wà, a ó sì máa dá wọn lóró tọ̀sán tòru láé àti láéláé.

Ka pipe ipin Ìfihàn 20

Wo Ìfihàn 20:10 ni o tọ