Ìfihàn 20:9 BMY

9 Wọ́n sì gòkè lọ la ibú ayé já, wọ́n sì yí ibùdó àwọn ènìyàn mímọ́ ká àti ìlú àyànfẹ́ náà: iná sì ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, ó sì jó wọn run.

Ka pipe ipin Ìfihàn 20

Wo Ìfihàn 20:9 ni o tọ