8 Yóò sì jáde lọ láti máa tan àwọn orílẹ̀-èdè tí ń bẹ ní igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé jẹ, Gógù àti Mágógú, láti gbá wọn jọ sí ogun: àwọn tí iyè wọn dàbí iyanrìn òkun.
Ka pipe ipin Ìfihàn 20
Wo Ìfihàn 20:8 ni o tọ