Ìfihàn 21:23 BMY

23 Ìlú náà kò sì ní oòrùn, tàbí òṣùpá, láti máa tan ìmọ́lẹ̀ sí i: nítorí pé ògo Ọlọ́run ni ó ń tàn ìmọ́lẹ̀ sí i, Ọ̀dọ́-Àgùntàn sì ni fìtílà rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 21

Wo Ìfihàn 21:23 ni o tọ