Ìfihàn 21:24 BMY

24 Àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì máa rìn nípa ìmọ́lẹ̀ rẹ̀: àwọn ọba ayé sì ń mú ògo wọn wá sínú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 21

Wo Ìfihàn 21:24 ni o tọ