Ìfihàn 6:12 BMY

12 Nígbà tí ó sì ṣí èdìdì kẹfa mo sì rí i, sì kíyèsí i, ìsẹ̀lẹ̀ ńlá kan ṣẹ̀; ọ̀run sì dúdú bí aṣọ ọ̀fọ̀ onírun, òsùpá sì dàbí ẹ̀jẹ̀;

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:12 ni o tọ