Ìfihàn 6:13 BMY

13 Àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run sì ṣubú sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí igi ọ̀pọ̀tọ́ tí ń rẹ̀ àìgbó èso rẹ̀ dànù, nígbà tí ẹ̀fúùfù ńlá bá mì í.

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:13 ni o tọ