Jòhánù 1:18 BMY

18 Kò sí ẹni tí ó rí Ọlọ́run rí, ṣùgbọ́n Òun, àní Àyànfẹ́ rẹ̀ kan ṣoṣo, tí ń bẹ ní oókan àyà Baba, Òun náà ni ó fi í hàn.

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:18 ni o tọ