Jòhánù 1:19 BMY

19 Èyí sì ni ẹ̀rí Jòhánù, nígbà tí àwọn Júù rán àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì láti Jérúsálẹ́mù wá láti béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ ẹni tí òun ń ṣe.

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:19 ni o tọ