Jòhánù 1:20 BMY

20 Òun kò sì kùnà láti jẹ́wọ́, ṣùgbọ́n òun jẹ́wọ́ wọ́ọ́rọ́wọ́ pé, “Èmi kì í ṣe Kírísítì náà.”

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:20 ni o tọ