Jòhánù 10:34 BMY

34 Jésù dá wọn lóhùn pé, “A kò ha tí kọ ọ́ nínú òfin yín pé, ‘Mo ti wí pé, Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́’?

Ka pipe ipin Jòhánù 10

Wo Jòhánù 10:34 ni o tọ