Jòhánù 13:15 BMY

15 Nítorí mo fi àpẹẹrẹ fún yín, kí ẹ̀yin lè máa ṣe gẹ́gẹ́ bí mo ti ṣe sí yín.

Ka pipe ipin Jòhánù 13

Wo Jòhánù 13:15 ni o tọ