Jòhánù 16:14 BMY

14 Òun ó máa yìn mí lógo: nítorí tí yóò gbà nínú ti èmi, yóò sì máa sọ ọ́ fún yín.

Ka pipe ipin Jòhánù 16

Wo Jòhánù 16:14 ni o tọ