Jòhánù 16:15 BMY

15 Ohun gbogbo tí Baba ní tèmi ni: nítorí èyí ni mo ṣe wí pé, òun ó gba nínú tèmi, yóò sì sọ ọ́ fún yín.

Ka pipe ipin Jòhánù 16

Wo Jòhánù 16:15 ni o tọ