Jòhánù 17:10 BMY

10 Tìrẹ sáà ni gbogbo ohun tí í ṣe tèmi, àti tèmi sì ni gbogbo ohun tí í ṣe tìrẹ, a sì ti ṣe mí lógo nínú wọn.

Ka pipe ipin Jòhánù 17

Wo Jòhánù 17:10 ni o tọ