Jòhánù 18:13 BMY

13 Wọ́n kọ́kọ́ fà á lọ sọ́dọ̀ Ánnà; nítorí òun ni àna Káyáfà, ẹni tí í ṣe olórí àlùfáà ní ọdún náà.

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:13 ni o tọ