Jòhánù 18:14 BMY

14 Káyáfà sáà ni ẹni tí ó ti bá àwọn Júù gbìmọ̀ pé, ó ṣàǹfàní kí ènìyàn kan kú fún àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:14 ni o tọ