Jòhánù 19:11 BMY

11 Jésù dá a lóhùn pé, “Ìwọ kì bá tí ní agbára kan lórí mi, bí kò se pé a fi í fún ọ láti òkè wá: nítorí náà ẹni tí ó fi mí lé ọ lọ́wọ́ ni ó ní ẹ̀ṣẹ̀ pọ̀ jù.”

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:11 ni o tọ