Jòhánù 19:10 BMY

10 Nítorí náà, Pílátù wí fún un pé, “Èmi ni ìwọ kò fọhùn sí? Ìwọ kò mọ̀ pé, èmi ní agbára láti dá ọ sílẹ̀, èmi sì ní agbára láti kàn ọ́ mọ́ àgbélébùú?”

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:10 ni o tọ