Jòhánù 19:9 BMY

9 Ó sì tún wọ inú gbọ̀ngàn ìdájọ́ lọ, ó sì wí fún Jésù pé, “Níbo ni ìwọ ti wá?” Ṣùgbọ́n Jésù kò dá a lóhùn.

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:9 ni o tọ