18 Níbití wọ́n gbé kàn án mọ́ àgbélébùú, àti àwọn méjì mìíràn pẹ̀lú rẹ̀, níhà ìhín àti níhà kejì, Jésù sì wà láàárin.
Ka pipe ipin Jòhánù 19
Wo Jòhánù 19:18 ni o tọ