Jòhánù 19:19 BMY

19 Pílátù sì kọ ìwé kan pẹ̀lú, ó sì fi í lé e lórí àgbélébùú náà. Ohun tí a sì kọ ni, JÉSÙ TI NÁSÁRẸ́TÌ ỌBA ÀWỌN JÚÙ.

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:19 ni o tọ