Jòhánù 19:4 BMY

4 Pílátù sì tún jáde, ó sì wí fún wọn pé, “Wò ó, mo mú u jáde tọ̀ yín wá, kí ẹ̀yin kí ó lè mọ̀ pé, èmi kò rí ẹ̀ṣẹ̀ kan lọ́wọ́ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:4 ni o tọ