Jòhánù 19:5 BMY

5 Nítorí náà Jésù jáde wá, ti òun ti adé ẹ̀gún àti aṣọ elésèé àlùkò. Pílátù sì wí fún wọn pé, Ẹ wò ọkùnrin náà!

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:5 ni o tọ