Jòhánù 19:40 BMY

40 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gbé òkú Jésù, wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ dì í pẹ̀lú tùràrí, gẹ́gẹ́ bí ìṣe àwọn Júù ti rí ní ìsìnkú wọn.

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:40 ni o tọ