Jòhánù 19:41 BMY

41 Àgbàlá kan sì wà níbi tí a gbé kàn án mọ́ àgbélébùú; ibojì titun kan sì wà nínú àgbàlá náà, nínú èyí tí a kò tíì tẹ́ ẹnìkan sí rí.

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:41 ni o tọ