Jòhánù 20:24 BMY

24 Ṣùgbọ́n Tómásì, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, tí a ń pè ní Dídímù, kò wà pẹ̀lú wọn nígbà tí Jésù dé.

Ka pipe ipin Jòhánù 20

Wo Jòhánù 20:24 ni o tọ