Jòhánù 21:24 BMY

24 Èyí ni ọmọ-ẹ̀yìn náà, tí ó jẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí, tí ó sì kọ̀wé nǹkan wọ̀nyí àwa sì mọ̀ pé, òtítọ́ ni ẹ̀rí rẹ̀.

Ka pipe ipin Jòhánù 21

Wo Jòhánù 21:24 ni o tọ