Jòhánù 4:22 BMY

22 Ẹ̀yin ń sin ohun tí ẹ̀yin kò mọ̀: àwa ń sin ohun tí àwa mọ̀: nítorí ìgbàlà ti ọ̀dọ̀ àwọn Júù wá.

Ka pipe ipin Jòhánù 4

Wo Jòhánù 4:22 ni o tọ