Jòhánù 4:23 BMY

23 Ṣùgbọ́n àkókò ń bọ̀, ó sì dé tán nísinsìn yìí, nígbà tí àwọn olùsìn tòótọ́ yóò máa sin Baba ní ẹ̀mí àti ní òtítọ́: nítorí irú wọn ni Baba ń wá kí ó máa sin òun.

Ka pipe ipin Jòhánù 4

Wo Jòhánù 4:23 ni o tọ