28 Nígbà náà ni wọ́n wí fún wọn pé, “Kín ni àwa ó ha ṣe, kí a lè ṣe iṣẹ́ Ọlọ́run?”
Ka pipe ipin Jòhánù 6
Wo Jòhánù 6:28 ni o tọ