29 Jésù dáhùn, ó sì wí fún wọn pé, “Èyí ni iṣe Ọlọ́run pé, kí ẹ̀yin gba ẹni tí ó rán an gbọ́.”
Ka pipe ipin Jòhánù 6
Wo Jòhánù 6:29 ni o tọ