Diutaronomi 1:23 BM

23 “Ọ̀rọ̀ yín dára lójú mi, mo sì yan ọkunrin mejila láàrin yín, ọkunrin kọ̀ọ̀kan láàrin ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Diutaronomi 1

Wo Diutaronomi 1:23 ni o tọ