Diutaronomi 10:6 BM

6 (Àwọn eniyan Israẹli rìn láti Beeroti Benejaakani lọ sí Mosera, ibẹ̀ ni Aaroni kú sí, tí wọ́n sì sin ín sí. Eleasari ọmọ rẹ̀ sì ń ṣe iṣẹ́ alufaa dípò rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 10

Wo Diutaronomi 10:6 ni o tọ