Diutaronomi 13:11 BM

11 Gbogbo ọmọ Israẹli yóo gbọ́, ẹ̀rù yóo sì bà wọ́n, ẹnikẹ́ni kò sì ní hu irú ìwà burúkú bẹ́ẹ̀ mọ́ láàrin yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 13

Wo Diutaronomi 13:11 ni o tọ