Diutaronomi 15:20 BM

20 Níbikíbi tí OLUWA Ọlọrun yín bá yàn, ni ẹ ti gbọdọ̀ máa jẹ wọ́n níwájú rẹ̀, ní ọdọọdún; ẹ̀yin ati gbogbo ilé yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 15

Wo Diutaronomi 15:20 ni o tọ