Diutaronomi 15:8 BM

8 Ẹ gbọdọ̀ lawọ́ sí i, kí ẹ sì yá a ní ohun tí ó tó láti tán gbogbo àìní rẹ̀, ohunkohun tí ó wù kí ó lè jẹ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 15

Wo Diutaronomi 15:8 ni o tọ