Diutaronomi 16:2 BM

2 Ẹ níláti máa rú ẹbọ àjọ ìrékọjá sí OLUWA Ọlọrun yín láti inú agbo mààlúù yín, tabi agbo aguntan yín, níbi tí ó bá yàn pé kí ẹ ti máa sin òun.

Ka pipe ipin Diutaronomi 16

Wo Diutaronomi 16:2 ni o tọ