Diutaronomi 17:2 BM

2 “Bí ọkunrin kan tabi obinrin kan láàrin àwọn ìlú tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín bá ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA Ọlọrun yín, nípa pé ó da majẹmu rẹ̀,

Ka pipe ipin Diutaronomi 17

Wo Diutaronomi 17:2 ni o tọ