Diutaronomi 18:12 BM

12 Ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe àwọn nǹkan tí a dárúkọ wọnyi di ohun ìríra níwájú OLUWA, ati pé nítorí ohun ìríra wọnyi ni OLUWA Ọlọrun yín ṣe ń lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde fun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 18

Wo Diutaronomi 18:12 ni o tọ