Diutaronomi 18:18 BM

18 N óo gbé wolii kan dìde gẹ́gẹ́ bíì rẹ, láàrin àwọn arakunrin wọn, n óo fi ọ̀rọ̀ mi sí i lẹ́nu, yóo sì máa sọ ohun gbogbo tí mo bá pa láṣẹ fún wọn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 18

Wo Diutaronomi 18:18 ni o tọ